Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

“Jèhófà Mú Kí Wọ́n Máa Yọ̀”

Láìka àtakò sí, Serubábélì, Jóṣúà Àlùfáà Àgbà àtàwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó dé láti ìgbèkùn lo ìgboyà, wọ́n sì nígbàgbọ́ nínú Jèhófà, èyí mú kí wọ́n borí àtakò, kí wọ́n sì láyọ̀. Ìtàn yìí wà nínú Ẹ́sírà 1:1-6; 3:1-6, 10-13; 4:1-7, 11-16; 5:3-5; 6:6-12, 22; Hágáì 1:2-11; 2:3-9; Sekaráyà 1:12-16; 2:7-9; 3:1, 2; 4:6, 7.