ILÉ ÌṢỌ́ No. 6 2016 | Àwọn Wo Ló Ń Gbé Ní Ọ̀run?

Rí àwọn nǹkan tí a kò lè fojú lásán rí látinú Bíbélì.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àwọn Wo Ló Wà Ní Ọ̀run?

Ṣé ó ṣeé ṣe kí a rí ìdáhùn tó ṣeé gbára lé.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àwọn Ìran Tó Sọ Àwọn Tó Ń Gbé Ní Ọ̀run

Kí lohun tí Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ nípa Jèhófà Ọlọ́run, Jésù Kristi, àtàwọn áńgẹ́lì olóòótọ́?

Ẹ̀kọ́ Tá A Rí Kọ́ Lára Àwọn Ẹyẹ Ojú Ọ̀run

Kì í ṣe pé àwọn ẹyẹ fi iṣẹ́ ọwọ́ Ọlọ́run hàn nìkan ni, wọ́n tún jẹ́ ká ronú nípa àwọn ohun tó ṣe pàtàkì jù.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Bó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Mi Ò Ní Apá

Ọkùnrin kan ṣèṣe gan-⁠an nínú jàǹbá burúkú kan, síbẹ̀ ó rí ìdí tó fi yẹ kó gbà gbọ́ pé Ọlọ́run wà.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ṣé Ọlọ́run máa gbọ́ kó sì dáhùn àdúrà rẹ?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Ọlọ́run Ló Dá Èṣù?

Ohun tí Bíbélì sọ bọ́gbọ́n mu, ó sì tuni lára.