Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. 1. Báwo la ṣe lè ‘máa retí Jèhófà’? (Sm. 130:5, 6)

  2. 2. Báwo la ṣe lè máa retí Jèhófà nígbà ìṣòro? (Háb. 2:3, 4; 2 Tím. 4:2; Lúùkù 2:36-38)

  3. 3. Báwo la ṣe lè máa fọgbọ́n lo àkókò wa bá a ṣe ń retí ọjọ́ Jèhófà? (2 Pét. 3:11-13)

  4. 4. Kí nìdí tó fi yẹ kọ́kàn wa balẹ̀ bá a ṣe ń retí Jèhófà lásìkò tá a bá dojú kọ ìṣòro? (Sm. 62:1, 2, 8, 10; 68:6; 130:2-4)

  5. 5. Kí ló yẹ ká ṣe ká lè gba ‘èrè tó wà fún olódodo’? (Sm. 58:11)

© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

CA-copgm24-YR