Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìlera

Ìlera

Ohun Tó Máa Mú Kí Ìlera Rẹ Dára Sí I

Ohun márùn-ún tó o lè ṣe báyìí kí ìlera rẹ lè dára sí i

Bá A Ṣe Lè Dènà Àrùn

Ojoojúmọ́ ni àgọ́ ara wa ń wọ̀yá ìjà pẹ̀lú àwọn kòkòrò àrùn tá ò lè rí.

Sùúrù Ń Mú Káyé Ẹni Dáa Sí I

A máa jàǹfààní tó pọ̀ tá a bá ń ṣe sùúrù tá a sì ń kápá ìmọ̀lára wa.

Ohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀​​—Ìlera àti Ìfaradà

Ṣé téèyàn bá ní àìlera, ó túmọ̀ sí pé èèyàn lè láyọ̀ mọ́ láé?

Bó O Ṣe Lè Dáàbò Bo Ara Ẹ Lọ́wọ́ Àwọn Ìsọfúnni Tí Kì Í Ṣòótọ́

Ìròyìn tó ń ṣi ni lọ́nà, ìròyìn èké àti àhesọ ọ̀rọ̀ pọ̀ káàkiri, wọ́n sì lè ṣàkóbá fúnni.

Ohun Méje Tí Ò Ní Jẹ́ Kí Oúnjẹ Léwu Táá sì Ṣara Lóore

Ìwàláàyè jẹ́ ẹ̀bùn, a sì ń fi hàn pé a mọrírì rẹ̀ tá a bá ń bójú tó ìlera wa àti ti ìdílé wa. Ronú nípa ọ̀nà tó o lè gbà ṣe bẹ́ẹ̀.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dín Bí Mo Ṣe Sanra Kù?

Má ṣe rò pé oúnjẹ àrà ọ̀tọ̀ kan ló máa dín bó o ṣe sanra kù, kàkà bẹ́ẹ̀, kọ́ ọ̀nà ìgbésí ayé tó yàtọ̀.

Àwọn Ọ̀dọ́ Sọ̀rọ̀ Nípa Ìlera

Ṣé ó máa ń ṣòro fún ẹ láti ṣọ́ ohun tí wàá jẹ, kó o sì ṣeré ìmárale? Nínú fídíò yìí, àwọn ọ̀dọ́ sọ̀rọ̀ nípa ohun tí wọ́n máa ń ṣe kí wọ́n lè nílera tó dáa.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Jẹ Oúnjẹ Tó Ṣara Lóore?

Àwọn tí oúnjẹ tí kò ṣara lóore bá mọ́ lára nígbà tí wọ́n wà lọ́dọ̀ọ́ máa ń bá a lọ títí wọ́n á fi dàgbà.

Ó Mú Káyé Ẹni Dára Sí I​—Ìlera Tó Dáa

Àwọn ìlànà Bíbélì ń kọ́ wa bá a ṣe lè máa tọ́jú ara wa.

Bó O Ṣe Lè Dàgbà Lọ́nà Tó Ń Yẹni

Àwọn ohun mẹ́fà kan wà tí Bíbélì sọ, tó máa jẹ́ kó o mu ara rẹ bá ipò tó wà báyìí mu.

Bó O Ṣe Lè Fara Da Àìsàn

Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Àìsàn Bá Dé Láìròtẹ́lẹ̀

Àwọn ìsọfúnni tó wúlò wo ló wà nínú Bíbélì tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí ìlera rẹ bá burú sí i láìròtẹ́lẹ̀?

Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Mí Lọ́wọ́ Tí Mo Bá Ń Ṣàìsàn Ọlọ́jọ́ Pípẹ́?

Bẹ́ẹ̀ ni! Kọ́ nípa ohun mẹ́ta tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti fara da àìsàn ọlọ́jọ́ pípẹ́.

Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Tó Ní Àárẹ̀ Ọpọlọ Lọ́wọ́

Tó o bá múra tán láti ran èèyàn ẹ tó ní àárẹ̀ ọpọlọ lọ́wọ́, ó máa rọrùn fún un láti lè máa fara dà á.

Tí Àìsàn Burúkú Bá Ń Ṣe Ẹ́, Sé Ayé Rẹ Ṣì Lè Dùn?

Kọ́ nípa ohun tó ti ran àwọn kan lọ́wọ́ nígbà tí wọ́n ń sàìsàn tó le koko.

Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Ní Àìsàn Tó Ò Ń Bá Fínra? (Apá 1)

Àwọn ọ̀dọ́ mẹ́rin sọ ohun tó ń jẹ́ kí wọ́n lè máa fara da àìsàn tó ń ṣe wọ́n, kínú wọn sì máa dùn.

Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Ní Àìsàn Tó Ò Ń Bá Fínra? (Apá 2)

Ka ìrírí táwọn ọ̀dọ́ kan tó ń ṣàìsàn tó le fẹnu ara wọn sọ nípa bí wọ́n ṣe ń fayọ̀ fara da ohun tó ń ṣe wọ́n.

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Mo Bá Ní Àìsàn tí Mò Ń Bá Fínra? (Apá 3)

Ohun táwọn ọ̀dọ́ mẹ́ta sọ lè jẹ́ kó o mọ bí wàá ṣe máa fara dà á.

Bó O Ṣe Lè Fara Da Àìlera

Bí Mo Tiẹ̀ Jẹ́ Aláìlera, Okun Inú Ń Gbé Mi Ró

Obìnrin kan tó wà lórí kẹ̀kẹ́ arọ máa ń rí “agbára tí ó ré kọjá ìwọ̀n ti ẹ̀dá” nítorí ìgbàgbọ́ rẹ̀.

Oju Jairo—Mu Ko Le Sin Olorun

Inu Jairo maa n dun, igbesi aye re si nitumo laika pe arun inu opolo to le ju lo n ba a finra.

Sísin Ọlọ́run Ni Oògùn Àìsàn Rẹ̀!

Wọ́n bí Onesmus pẹ̀lú àìsàn osteogenesis imperfecta tí kì í jẹ́ kí egungun lágbára. Báwo ni àwọn ìlérí tí Ọlọ́run ṣe tó wà nínú Bíbélì ṣe ràn án lọ́wọ́?

Ọwọ́ Ni Mo Fi Ń Ṣe Gbogbo Nǹkan

Wọ́n bí James Ryan ní afọ́jú, nígbà tó yá, ó di adití. Kí ló mú kí ìgbésí ayé rẹ̀ nítumọ̀?

Fídíò Kékeré: “Ọpẹ́lọpẹ́ Rẹ̀ Lára Mi”

Wo fídíò yìí tó dá lórí ọkùnrin afọ́jú kan tó jàǹfààní nínú Bíbélì tí wọ́n ṣe fún àwọn afọ́jú.

Jèhófà Fi Àánú Hàn Sí Mi Ju Bí Mo Ṣe Rò Lọ

Félix Alarcón rí nǹkan gidi fi ìgbésí ayé rẹ̀ ṣe lẹ́yìn tí ìjàǹbá alùpùpù mú kó rọ lápá àtẹsẹ̀.

Ìtọ́jú

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí A Ṣe Lè Tọ́jú Àwọn Òbí Wa Tó Ti Dàgbà?

Bíbélì sọ àpẹẹrẹ àwọn ọkùnrin àti obìnrin tó nígbàgbọ́ tó ṣe bẹ́ẹ̀. Ó tún jẹ́ ká rí àwọn ìmọ̀ràn tó gbéṣẹ́ tó lè ṣèrànwọ́ fún àwọn tó ń tọ́jú àwọn àgbàlagbà.

Ohun Tí Ẹ Lè Ṣe Tí Ọmọ Yín Bá Jẹ́ Abirùn

Jẹ́ ká wo àwọn ìṣòro mẹ́ta tó sábà máa ń jẹ yọ àti bí ọgbọ́n tó wà nínú Bíbélì ṣe lè mú kó o borí wọn.

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Òbí Mi Bá Ń Ṣàìsàn?

Ìwọ nìkan kọ́ nirú ẹ̀ ti ṣẹlẹ̀ sí. Wo ohun tó ran àwọn méjì lọ́wọ́.

Tí Àìsàn Gbẹ̀mí-Gbẹ̀mí Bá Ń Ṣe Ẹni Tá A Nífẹ̀ẹ́

Báwo làwọn mọ̀lẹ́bí ṣe lè ṣaájò ẹni tí àìsàn gbẹ̀mí-gbẹ̀mí ń ṣe kí wọ́n sì tù wọ́n nínú? Báwo lẹni tó ń tọ́jú aláìsàn náà ṣe lè fara da ọgbẹ́ ọkàn tí wọ́n máa ní láàárín àkókò náà?

Ààrùn àti Ìṣòro

Ohun Tó O Lè Ṣe tí Àjàkálẹ̀ Àrùn Bá Ṣẹlẹ̀

Tí àjàkálẹ̀ àrùn bá ṣẹlẹ̀, kí lo lè ṣe tí kò fi ní kó bá ìlera ẹ àti àjọṣe ẹ pẹ̀lú Ọlọ́run, tí wàá sì máa láyọ̀?

Àìtó Ẹ̀jẹ̀​—Ohun Tó Ń Fà Á, Bó Ṣe Máa Ń Ṣe Àwọn Tó Ní In àti Ìtọ́jú Rẹ̀

Kí là ń pè ní àìtó ẹ̀jẹ̀? Ṣé ó ṣeé dènà, ṣé ó sì ṣeé wò sàn?

Oúnjẹ Tó Gbòdì Lára Àtèyí Tí Kò Báni Lára Mu—Ṣó Yàtọ̀ Síra?

Ewu wo ló wà nínú kéèyàn fúnra rẹ̀ pinnu èyí tó ń ṣe òun?

Ìdààmú

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìsoríkọ́?

Kọ́ nípa ohun tó máa ń fa ìsoríkọ́ àti bí Bíbélì ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti kápá àwọn èrò tí kò tọ́.

Tí Ìṣòro Bá Pọ̀ Lápọ̀jù

Ayé rẹ ṣì máa dùn láìka ìṣòro sí.

Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ní Ìdààmú Ọkàn

Àpilẹ̀kọ yìí sọ ohun tó máa ń fà ìdààmú ọkàn àti bá a ṣe lè mọ̀ pé òun ló ń ṣe ẹnì kan. Wo ohun tí àwọn òbí àtàwọn mí ì lè ṣe.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Èrò Tí Kò Tọ́?

Tó o bá ń tẹ̀ lé àwọn àbá yìí wàá lè kọ́ béèyàn ṣe ń ronú lọ́nà tó tọ́.

Ìbànújẹ́ Túbọ̀ Ń Dorí Ọ̀pọ̀ Àwọn Ọ̀dọ́ Kodò​—Kí Ni Bíbélì Sọ?

Bíbélì sọ ohun táwọn ọ̀dọ́ lè ṣe tí ìbànújẹ́ bá dorí wọn kodò.

Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Mo Bá Ń Sorí Kọ́?

Àwọn àbá yìí máa jẹ́ kó o mọ ohun tó yẹ kó o ṣe kó o lè bọ́ nínú ẹ̀.

Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Mí Lọ́wọ́ Tí Mo Bá Ní Ìrẹ̀wẹ̀sì Ọkàn?

Àwọn ohun mẹ́ta kan wà tí Ọlọ́run máa ń fún wa ká lè fara da ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn.

Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ran Àwọn Tó Ń Ronú Àtipa Ara Wọn Lọ́wọ́?

Àwọn ìmọ̀ràn wo nínú Bíbélì ló wúlò fún ẹni táyé ti sú?

Ìdààmú àti Àìbalẹ̀ Ọkàn

Bó O Ṣe Lè Borí Àníyàn

Àwọn ìmọ̀ràn àtàwọn ẹsẹ Bíbélì wo ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí àníyàn?

Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ran Àwọn Ọkùnrin Tó Ń Ṣàníyàn Lọ́wọ́?

Àníyàn túbọ̀ ń pọ̀ sí i láwọn àkókò tí nǹkan le gan-an yìí. Ṣé Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tó o bá ń kojú ìṣòro àníyàn?

Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Ò Bá Lómìnira Àtijáde Bíi Ti Tẹ́lẹ̀

Tí ohùn kan bá ṣẹlẹ̀ tó ò sì lè kúrò nílé, má ṣe rò pé gbogbo nǹkan máa dàrú, pé o ò lè láyọ̀ àti pé ó lè má sí ọ̀nà àbáyọ.

Ohun Tó O Lè Ṣe Kí Àrùn Corona Má Bàa Jẹ́ Kí Nǹkan Tojú Sú Ẹ

Tá ò bá jà fitafita, ó lè bẹ̀rẹ̀ sí í sú wa láti dáàbò bo ara wa lọ́wọ́ àrùn Corona.

Bó O Ṣe Lè Kojú Àìbalẹ̀ Ọkàn

Wo àwọn ìlànà mélòó kan tó lè jẹ́ kó o kojú àìbalẹ̀ ọkàn tàbí kó o dín in kù.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Borí Àníyàn?

Àwọn ohun mẹ́fà tó máa jẹ́ kí àníyàn ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí kò sì ní pa ẹ́ lára.

Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Borí Àníyàn?

Ó jọ pé ara ìgbésí ayé àwa èèyàn ni ṣíṣe àníyàn jẹ́. Ǹjẹ́ a lè bọ́ lọ́wọ́ àníyàn?

Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Àníyàn

Àníyàn tó dáa lè ṣàǹfààní; àmọ́ èyí tí kò dáa lè fa ìpalára. Bó o ṣe lè kojú rẹ̀, kó o sì ṣàṣeyọrí?

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Kò Fi Ní Máa Rẹ̀ Mí Jù?

Kí ló lè fà á tó fi máa rẹni gan-an? Ṣé ó máa ń rẹ̀ ẹ́ gan-an? Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, kí lo lè ṣe nípa rẹ̀?

Ṣé Gbogbo Nǹkan Ni Mo Máa Ń Fẹ́ Ṣe Láìṣe Àṣìṣe Kankan?

Báwo lo ṣe lè fìyàtọ̀ sáàárín kó o máa ṣe gbogbo ohun tó o lè ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ẹ àti kó o máa lé ohun tí ọwọ́ ẹ̀ ò lè tẹ̀?

Ohun tó o lè ṣe tí àyípadà bá ṣẹlẹ̀

Ìyípadà gbọ́dọ̀ wáyé. Wo ohun tí àwọn kan ti ṣe láti fara dà á.

Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Kò Já Mọ́ Nǹkan Kan

Ohun mẹ́ta tó o lè ṣe láti níyì lójú ara wa.

Ìtọ́jú Ìlera

Ṣé Kristẹni Lè Gba Ìtọ́jú Lọ́dọ̀ Àwọn Dókítà?

Ǹjẹ́ irú ìtọ́jú tá a pinnu láti gbà ṣe pàtàkì lójú Ọlọ́run?

Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Èèyàn Rẹ Bá Ń Ṣàìsàn

Ìdààmú máa ń bá ẹnì tó bá lọ rí dókítà tàbí tí wọ́n dá dúró sí ilé ìwòsàn. Báwo lo ṣe lè ran èèyàn rẹ tó wà nírú ipò yìí lọ́wọ́?