ERÉ ALÁWÒRÁN Sólómọ́nì Hùwà Ọlọgbọ́n TẸ̀ Ẹ̣́ Wa eré aláwòrán yìí jáde kí o sì tẹ̀ ẹ́, kẹ́ ẹ fi kẹ́kọ̀ọ́ nípa Sólómọ́nì Ọba. O Tún Lè Wo ERÉ ALÁWÒRÁN Ta Ló Yàn Láti Sin Jèhófà? Eré yìí máa ran àwọn ọmọ ọdún mẹ́fà sí mẹ́jọ kí wọ́n lè mọ àwọn èèyàn inú Bíbélì. ERÉ ALÁWÒRÁN Hánà Ran Sámúẹ́lì Lọ́wọ́ Kó Lè Sin Jèhófà Eré yìí máa ran àwọn ọmọ ọdún mẹ́ta sí mẹ́fà láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ẹ̀bùn tí Hánà máa ń fún Sámúẹ́lì lọ́dọọdún. ERÉ ALÁWÒRÁN Dáfídì Nígboyà, Bí Ò Tiẹ̀ Ní Ju Ohun Ìjà Díẹ̀ Mú káàdì tí wọ́n ya àwọn èèyàn inú Bíbélì sí tó bára mu pẹ̀lú èyí tí wọ́n ya àwòrán àwọn nǹkan míì sí. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Sólómọ́nì Hùwà Ọlọgbọ́n ERÉ ALÁWÒRÁN Sólómọ́nì Hùwà Ọlọgbọ́n Yorùbá Sólómọ́nì Hùwà Ọlọgbọ́n https://assetsnffrgf-a.akamaihd.net/assets/ct/2208d1720a/images/syn_placeholder_sqr.png