Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

A Fẹ́ Kó O Wá Sí Àpéjọ ‘Ẹ Máa Ní Sùúrù’! ti Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti Ọdún 2023

A Fẹ́ Kó O Wá Sí Àpéjọ ‘Ẹ Máa Ní Sùúrù’! ti Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti Ọdún 2023

Ó yẹ ká túbọ̀ máa ṣe sùúrù ju ti ìgbàkígbà rí lọ. Àmọ́ kí ló máa fi hàn pé ẹnì kan ní sùúrù? Báwo ni sùúrù ṣe máa ṣe wá láǹfààní nínú ìgbésí ayé wa ojoojúmọ́? Wàá rí ìdáhùn àwọn ìbéèrè yìí tó o bá wá sí Àpéjọ Agbègbè ‘Ẹ Máa Ní Sùúrù’! ti ọdún 2023.