Ìsọfúnni Ṣókí—Myanmar
- 56,145,000—Iye àwọn èèyàn
- 5,171—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 96—Iye àwọn ìjọ
- 10,962—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Myanmar
Kí ló mú kí ọ̀pọ̀ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà fi ìlú wọn sílẹ̀ kí wọ́n lè ṣe nínú iṣẹ́ ìkórè tó ń lọ ní Myanmar?
ÀWỌN ÌPÀDÉ PÀTÀKÌ
Ó Ń Ṣe Wá Bíi Kípàdé Náà Má Parí
Wo ojúlówó ìfẹ́ àti ìṣọ̀kan tó wà láàárín àwọn tó wá látinú oríṣiríṣi ẹ̀yà, èdè, àtorílẹ̀-èdè ní àkànṣe Àpéjọ Àgbègbè tá a ṣe nílùú Yangon, Myanmar.