Bá A Ṣe Ń Ran Ará Ìlú Lọ́wọ́

BÁ A ṢE Ń RAN ARÁ ÌLÚ LỌ́WỌ́

À Ń Ran Àwọn Adití Lọ́wọ́ ní “Orílẹ̀-èdè Tó Rẹwà Jù ní Agbedeméjì Ayé”

Ìdálẹ́kọ̀ọ́ tó dá lórí Bíbélì ń ran àwọn adití lọ́wọ́ ní Indonéṣíà.

BÁ A ṢE Ń RAN ARÁ ÌLÚ LỌ́WỌ́

À Ń Ran Àwọn Adití Lọ́wọ́ ní “Orílẹ̀-èdè Tó Rẹwà Jù ní Agbedeméjì Ayé”

Ìdálẹ́kọ̀ọ́ tó dá lórí Bíbélì ń ran àwọn adití lọ́wọ́ ní Indonéṣíà.

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ń Kọ́ Àwọn Òbí Àtàwọn Ọmọ Nítorí Àwọn Tó Ń Bá Ọmọdé Ṣèṣekúṣe

Ọjọ́ pé táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ń tẹ àwọn ìwé tó ń sọ bí ìdílé ṣe lè láyọ̀, tí wọ́n sì ń pín àwọn ìwé náà káàkiri.

Àwọn Tó Ń Dáni Lẹ́kọ̀ọ́ ní Philippines Rí Ìwúlò Ìkànnì JW.ORG

Kí ni àwọn olùkọ́ àtàwọn agbani-nímọ̀ràn tó lé ní ẹgbẹ̀rún kan kọ́ nípa ìkànnì yìí?

Ìtùnú àti Ojúlówó Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Aláìsàn

Báwo ni àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ń fìfẹ́ hàn sí àwọn ará wọn tó ń ṣàìsàn tó le?

Àǹfààní Wo Ni Gbọ̀ngàn Ìjọba Máa Ṣe Àdúgbò Yín?

Gbọ́ ohun táwọn aládùúgbò sọ nípa bó ṣe rí lára wọn pé Gbọ̀ngàn Ìjọba wà ládùúgbò wọn.

Wọ́n Ń Tu Àwọn Arúgbó Nínú, Wọ́n sì Ń Fún Wọn Nírètí

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń lọ ṣèbẹ̀wò sí ilé tí wọ́n ti ń tọ́jú arúgbó ní Ọsirélíà.

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Italy Ran Àwọn Aládùúgbò Wọn Lọ́wọ́

Irú ìrànlọ́wọ́ wo ni wọ́n nílò? Kí ni àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe?

Àkànṣe Iṣẹ́ ìwàásù Gbẹ̀mí Àwọn Èèyàn Là

Kí nìdí táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà fi ṣètò àkànṣe iṣẹ́ ìwàásù olóṣù méjì ní ìlú Tabasco lórílẹ̀-èdè Mexico? Àṣeyọrí wo ni wọ́n ṣe?

Ìgbàgbọ́ Wọn Ò Mì Nígbà Tí Ìjì Jà ní Philippines

Àwọn tó làá já sọ ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà tí ìjì líle tí wọ́n ń pè ní Super Typhoon Haiyan jà.

Tí Àjálù Bá Ṣẹlẹ̀, Ìfẹ́ Máa Ń Mú Ká Ṣèrànwọ́

Onírúurú orílẹ̀-èdè làwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti máa ń ṣèrànwọ́ nígbà àjálù.

Wọ́n Mára Tu Àwọn Èèyàn Níbi Eré Ìdárayá Tour de France

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà gbé àwọn àtẹ ìwé tó ṣeé tì kiri lọ sáwọn ìlú táwọn èèyàn ti ṣeré ìdárayá Tour de France, kí wọ́n lè fi ọ̀rọ̀ ìtùnú táá jẹ́ kí wọ́n nírètí hàn wọ́n.

Wọ́n Ń Ran Àwọn tí Ogun Lé Wá sí Àárín Gbùngbùn Yúróòpù Lọ́wọ́

Kì í ṣe oúnjẹ, aṣọ àti ilé nìkan làwọn tí ogun lé kúrò nílùú nílò. Àwọn Ẹlẹ́rìí tó yọ̀ǹda ara wọn ń sọ̀rọ̀ ìtùnú àti ọ̀rọ̀ táá jẹ́ kí wọ́n nírètí fún wọn látinú Bíbélì.

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kọ́wọ́ Ti Àwọn Aráàlú Láti Tún Ìlú Rostov-on-Don Ṣe

Ìjọba ìlú Rostov-on-Don, lórílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà kọ lẹ́tà sáwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà láti dúpẹ́ lọ́wọ́ wọn fún iṣẹ́ tí wọ́n ṣe nígbà táwọn èèyàn ń tún ìlú náà ṣe nígbà ìrúwé.

Mo Rìnnà Kore Lọ́gbà Ẹ̀wọ̀n

Ọkùnrin kan tó ń jẹ́ Donald, tó jẹ́ ẹlẹ́wọ̀n nígbà kan sọ bí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ṣe jẹ́ kó mọ Ọlọ́run, tó yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà, tó sì wá di ọkọ rere.