Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Palestinian Territories

 

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Ilẹ̀ Palẹ́sínì

  • Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—78

  • Iye àwọn ìjọ​—2

  • Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi​—213

  • Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún​—72,237

  • Iye èèyàn​—5,490,000

2016-09-27

PALESTINIAN TERRITORIES

Wọ́n Ń Fi Ẹ̀tọ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tó Wà ní Àgbègbè Palẹ́sínì Dù Wọ́n

Wọn ò gbà láti forúkọ ẹ̀sìn àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sílẹ̀ lábẹ́ òfin torí wọn ò ka ẹ̀sìn wọn sí, ìyẹn wá ń jẹ́ kí wọ́n máa fi ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn tí wọ́n ní dù wọ́n, kò sì yẹ kó rí bẹ́ẹ̀.