Apá 1 TẸ̀ Ẹ̣́ Apá 1 Ọ̀rọ̀ Àwòrán Ohun tó dá lé: Bí Bíbélì ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ àti bó o ṣe lè mọ Ọlọ́run tó fún wa ní Bíbélì Ẹ̀KỌ́ 01 Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́? 02 Bíbélì Sọ Pé Ọ̀la Ń Bọ̀ Wá Dáa 03 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Gbára Lé Bíbélì? 04 Ta Ni Ọlọ́run? 05 Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Bíbélì Ti Wá 06 Ṣé Ayé àti Ọ̀run Ní Ìbẹ̀rẹ̀? 07 Irú Ẹni Wo Ni Jèhófà? 08 Bó O Ṣe Lè Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà 09 Máa Gbàdúrà Kó O Lè Túbọ̀ Sún Mọ́ Ọlọ́run 10 Àǹfààní Tó O Máa Rí Ní Ìpàdé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà 11 Bó O Ṣe Lè Jàǹfààní Púpọ̀ Látinú Bíbélì 12 Ohun Tó O Lè Ṣe Láti Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Nìṣó Pa Dà Èyí Tó Kàn O Tún Lè Wo ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ Kí Ni Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn? Ìtumọ̀ Bíbélì èyíkéyìí tó bá wù ẹ́ lo lè lò láti fi kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. O sì lè pe gbogbo ìdílé ẹ tàbí kó o pe àwọn ọ̀rẹ́ ẹ wá síbi ìkẹ́kọ̀ọ́ náà. Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Apá 1 GBÁDÙN AYÉ RẸ TÍTÍ LÁÉ!—ÌJÍRÒRÒ LÁTINÚ BÍBÉLÌ Apá 1 Yorùbá Apá 1 https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1102021310/univ/art/1102021310_univ_sqr_xl.jpg lff