Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Mozambique

  • Bairro dos Pescadores, nítòsí Maputo, Mozambique​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń fi ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ lọni

Ìsọfúnni Ṣókí—Mozambique

  • 32,420,000—Iye àwọn èèyàn
  • 87,668—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,651—Iye àwọn ìjọ
  • 398—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ

Àpéjọ Agbègbè Lórí Tẹlifíṣọ̀n àti Rédíò

A gbé àpéjọ agbègbè 2020 sórí ìkànnì, àmọ́ ọ̀pọ̀ ní Màláwì àti Mòsáńbíìkì ò ní Íńtánẹ́ẹ̀tì. Báwo wá ni wọ́n ṣe wo àpéjọ náà?