Bá A Ṣe Ń Ná Owó Tẹ́ Ẹ Fi Ń Ṣètọrẹ

Ọrẹ àtinúwá la fi ń ti iṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lẹ́yìn. Wàá rí bá a ṣe ń lo ọrẹ yìí láti ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ kárí ayé.

Bá A Ṣe Ń Bójú Tó Àwọn Ilé Ìpàdé Wa

Kárí ayé, àwọn ilé tá a ti ń ṣèpàdé lé ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́ta (60,000). Báwo la ṣe ń bójú tó àwọn ilé yìí?

Iṣẹ́ Ìkọ́lé Tó Ń Jẹ́ Ká Lè Túbọ̀ Wàásù

Iṣẹ́ ìkọ́lé ń mú kí iṣẹ́ ìwàásù túbọ̀ máa tẹ̀ síwájú. Báwo la ṣe ń lo owó tẹ́ ẹ fi ń ṣètọrẹ láti kọ́ àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa ká sì tún wọn ṣe?

Àwọn Ilé Tó Ń Fògo fún Olùkọ́ Wa Atóbilọ́lá

Bawo lawon ile ta a n lo fawon ile eko eto Olorun se n se awon omo ile eko atawon oluko won lanfaani?

Àtẹ Ìwé Tó Ń Jẹ́rìí “fún Gbogbo Orílẹ̀-Èdè”

Àtẹ ìwé wa ò ṣòro dá mọ̀ kárí ayé. Báwo ni wọ́n ṣe ṣe é?

Bá A Ṣe Ṣèrànwọ́ Nígbà Àjálù Lọ́dún 2022—A Fi Hàn Pé A Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Ará

Báwo la ṣe ṣèrànwọ́ fáwọn tí àjálù ṣẹlẹ̀ sí lọ́dún 2022?

Bá A Ṣe Dáàbò Bo Àwọn Tó Wá sí Ilé Ìpàdé Wa Lásìkò Àrùn Kòrónà

A bẹ̀rẹ̀ sí í ṣèpàdé pa dà lójúkojú ní April 1, 2022. Wo àwọn nǹkan tá a ṣe láti dáàbò bo àwọn tó bá wá sílé ìpàdé wa kí wọ́n má lọ kó àrùn Kòróná.

Jèhófà Kò Gbàgbé Àwọn Adití

A ní fídíò lédè àwọn adití ní èdè tó ju ọgọ́rùn ún (100) lọ! Báwo la ṣe ń ṣe àwọn ìtẹ̀jáde yìí tá a sì ń pín in kiri?

A Ṣètò Ìrànwọ́ Lásìkò ‘Ogun, àti Ìròyìn Nípa Àwọn Ogun’

Ọ̀nà wo la gbà ń ṣètò ìrànwọ́ fáwọn ará wa lórílẹ̀-èdè Ukraine láìka ogun tó ń jà sí? Báwo lèyí sì ṣe rí lára wọn?

Ohun Tuntun Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀ Tá A Fi Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Àwọn ohun èlò tó yàtọ̀ sí èyí tá à ń lò tẹ́lẹ̀ la fi tẹ ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ka àpilẹ̀kọ yìí kó o lè mọ ìdí tá a fi ṣe bẹ́ẹ̀.

Bá A Ṣe Pèsè Ìrànwọ́ Lọ́dún 2021—A Ò Pa Àwọn Arákùnrin Àtàwọn Arábìnrin Wa Tì

Lọ́dún 2021, a ṣèrànwọ́ fáwọn ará wa láwọn orílẹ̀-èdè kan tí àrùn Corona àtàwọn àjálù míì ti fojú wọn rí màbo.

Ìròyìn Tó Ṣeé Gbára Lé Tó sì Ń Fún Ìgbàgbọ́ Ẹni Lókun

Àwọn ìròyìn orí Ìkànnì jw ti jẹ́ ká mọ bí nǹkan ṣe ń lọ fáwọn ará wa kárí ayé. Báwo la ṣe ń kó àwọn ìròyìn yìí jọ?

Àwọn Orin Tó Ń Jẹ́ Ká Túbọ̀ Sún Mọ́ Ọlọ́run

Ṣé o ní orin pàtó kan tó o máa ń gbádùn gan-an lára àwọn orin wa míì? Ṣé o ti rò ó rí pé báwo la ṣe ṣe é?

Ìwé Tó Ń Ṣe Àwọn Èèyàn Láǹfààní

Yàtọ̀ sí pé a máa ń ṣe ìwé àwọn afọ́jú, a tún máa ń kọ́ àwọn èèyàn bí wọ́n ṣe lè ka ìwé àwọn afọ́jú.

Ètò Ìṣiṣẹ́ Tó Ní Gbogbo Ohun Tá A Nílò

“Ẹ̀bùn àrà ọ̀tọ̀ gbáà” ni JW Library. Wàá rí bá a ṣe gbé e jáde àti bá a ṣe mú kó sunwọ̀n sí i.

Àpéjọ Agbègbè Lórí Tẹlifíṣọ̀n àti Rédíò

A gbé àpéjọ agbègbè 2020 sórí ìkànnì, àmọ́ ọ̀pọ̀ ní Màláwì àti Mòsáńbíìkì ò ní Íńtánẹ́ẹ̀tì. Báwo wá ni wọ́n ṣe wo àpéjọ náà?

A Ṣètò Ìrànwọ́ Fáwọn Ará Kárí Ayé Nígbà Àjàkálẹ̀ Àrùn

Àwọn ará àtàwọn tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọyì ètò ìrànwọ́ tá a ṣe nígbà àrùn Corona.

Àwọn Míṣọ́nnárì Ń Wàásù ní “Ibi Tó Jìnnà Jù Lọ ní Ayé”

Àwọn míṣọ́nnárì tó lé ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) ló ń sìn kárí ayé. Báwo la ṣe ń bójú tó wọn?

A Gbèjà Àwọn Ará Wa Kí Wọ́n Lè Ní Òmìnira Láti Jọ́sìn

Nígbà táwọn alátakò gbéjà ko àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, tí wọn ò sì fún wọn lómìnira láti jọ́sìn ní fàlàlà, àwọn ará gbégbèésẹ̀ ní kíá láti ràn wọ́n lọ́wọ́.

Àwọn Ará Ń Gbádùn Tẹlifíṣọ̀n JW Láwọn Ibi Tí Ò Ti Sí Íńtánẹ́ẹ̀tì

Báwo làwọn ará ní Áfíríkà ṣe ń wo ètò tẹlifíṣọ̀n JW láìlo íńtánẹ́ẹ̀tì?

Ọ́fíìsì Àwọn Atúmọ̀ Èdè Ń Ṣe Ọ̀pọ̀ Láǹfààní

Wàá rí bíṣẹ́ ìtúmọ̀ ṣe dáa sí i nígbà táwọn atúmọ̀ èdè kó lọ sáàárín àwọn tó ń sọ èdè tí wọ́n ń túmọ̀.

A Pèsè Ìrànwọ́ Fáwọn Tí Àjálù Ṣẹlẹ̀ Sí

Lọ́dún iṣẹ́ ìsìn 2020, àrùn Corona àtàwọn àjálù míì mú kí nǹkan nira fún ọ̀pọ̀ àwọn ará wa. Báwo la ṣe ràn wọ́n lọ́wọ́?

Ìwé Tó Ṣe Pàtàkì Jù Nínú Gbogbo Ìwé

Ohun tá à ń ṣe láti mú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun jáde kọjá ká tú u, ká tẹ̀ ẹ́, ká sì dì í pọ̀.

Àwọn Èèyàn Ń Jàǹfààní Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì Kárí Ayé

A ní ilé ẹ̀kọ́ pàtàkì kan tá à ń ṣe ní New York, àmọ́ ọ̀pọ̀ ibi kárí ayé làwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti ń wá síbẹ̀. Báwo làwọn akẹ́kọ̀ọ́ yìí ṣe ń débẹ̀?

Àwọn Iṣẹ́ Ìkọ́lé Tá A Ṣe Kí Àrùn Corona Tó Bẹ̀rẹ̀

A pinnu láti kọ́ tàbí ṣàtúnṣe sáwọn ibi ìjọsìn tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjì àti ọgọ́rùn-ún méje (2,700) láàárín ọdún iṣẹ́ ìsìn 2020. Báwo ni àrùn Corona ṣe dí àwọn iṣẹ́ náà lọ́wọ́?

Ohun Tó Ṣẹ́ Kù Níbì Kan Ń Dí Àìtó Àwọn Míì

Báwo la ṣe ń ṣètìlẹyìn fáwọn ará wa tó ń gbé láwọn orílẹ̀-èdè tí nǹkan ò ti ṣẹnuure?

Ẹ̀rọ Kékeré Tó Ń Mú Kí Ìgbàgbọ́ Àwọn Èèyàn Túbọ̀ Lágbára

Ní báyìí, ọ̀pọ̀ lára àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ló ti ń wa àwọn ìwé àtàwọn fídíò jáde lórí ìkànnì láìlo Íńtánẹ́ẹ̀tì.

A Túmọ̀ Àpéjọ Agbègbè “Ẹ Máa Yọ̀ Nígbà Gbogbo”! ti Ọdún 2020

Kí ló mú kó ṣeé ṣe fún wa láti tètè túmọ̀ àwọn àsọyé, fídíò àtàwọn orin sí èdè tó lé ní ọgọ́rùn-ún márùn-ún?

À Ń Ṣèpàdé Látorí Ẹ̀rọ Ayélujára

Báwo ni ètò Ọlọ́run ṣe ran ìjọ lọ́wọ́ kí wọ́n lè máa ṣèpàdé lórí ètò ìṣiṣẹ́ Zoom?

ÀWỌN OHUN TÁ A ṢE JÁDE

IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ ÀTI ÀBÓJÚTÓ RẸ̀

Bá A Ṣe Ń Bójú Tó Àwọn Ilé Ìpàdé Wa

Kárí ayé, àwọn ilé tá a ti ń ṣèpàdé lé ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́ta (60,000). Báwo la ṣe ń bójú tó àwọn ilé yìí?

Iṣẹ́ Ìkọ́lé Tó Ń Jẹ́ Ká Lè Túbọ̀ Wàásù

Iṣẹ́ ìkọ́lé ń mú kí iṣẹ́ ìwàásù túbọ̀ máa tẹ̀ síwájú. Báwo la ṣe ń lo owó tẹ́ ẹ fi ń ṣètọrẹ láti kọ́ àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa ká sì tún wọn ṣe?

Àwọn Ilé Tó Ń Fògo fún Olùkọ́ Wa Atóbilọ́lá

Bawo lawon ile ta a n lo fawon ile eko eto Olorun se n se awon omo ile eko atawon oluko won lanfaani?

Bá A Ṣe Dáàbò Bo Àwọn Tó Wá sí Ilé Ìpàdé Wa Lásìkò Àrùn Kòrónà

A bẹ̀rẹ̀ sí í ṣèpàdé pa dà lójúkojú ní April 1, 2022. Wo àwọn nǹkan tá a ṣe láti dáàbò bo àwọn tó bá wá sílé ìpàdé wa kí wọ́n má lọ kó àrùn Kòróná.

Ọ́fíìsì Àwọn Atúmọ̀ Èdè Ń Ṣe Ọ̀pọ̀ Láǹfààní

Wàá rí bíṣẹ́ ìtúmọ̀ ṣe dáa sí i nígbà táwọn atúmọ̀ èdè kó lọ sáàárín àwọn tó ń sọ èdè tí wọ́n ń túmọ̀.

Àwọn Iṣẹ́ Ìkọ́lé Tá A Ṣe Kí Àrùn Corona Tó Bẹ̀rẹ̀

A pinnu láti kọ́ tàbí ṣàtúnṣe sáwọn ibi ìjọsìn tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjì àti ọgọ́rùn-ún méje (2,700) láàárín ọdún iṣẹ́ ìsìn 2020. Báwo ni àrùn Corona ṣe dí àwọn iṣẹ́ náà lọ́wọ́?

IṢẸ́ ÀBÓJÚTÓ

A Gbèjà Àwọn Ará Wa Kí Wọ́n Lè Ní Òmìnira Láti Jọ́sìn

Nígbà táwọn alátakò gbéjà ko àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, tí wọn ò sì fún wọn lómìnira láti jọ́sìn ní fàlàlà, àwọn ará gbégbèésẹ̀ ní kíá láti ràn wọ́n lọ́wọ́.

Ohun Tó Ṣẹ́ Kù Níbì Kan Ń Dí Àìtó Àwọn Míì

Báwo la ṣe ń ṣètìlẹyìn fáwọn ará wa tó ń gbé láwọn orílẹ̀-èdè tí nǹkan ò ti ṣẹnuure?

IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ ÀTI KÍKỌ́NI

Àtẹ Ìwé Tó Ń Jẹ́rìí “fún Gbogbo Orílẹ̀-Èdè”

Àtẹ ìwé wa ò ṣòro dá mọ̀ kárí ayé. Báwo ni wọ́n ṣe ṣe é?

Àpéjọ Agbègbè Lórí Tẹlifíṣọ̀n àti Rédíò

A gbé àpéjọ agbègbè 2020 sórí ìkànnì, àmọ́ ọ̀pọ̀ ní Màláwì àti Mòsáńbíìkì ò ní Íńtánẹ́ẹ̀tì. Báwo wá ni wọ́n ṣe wo àpéjọ náà?

Àwọn Míṣọ́nnárì Ń Wàásù ní “Ibi Tó Jìnnà Jù Lọ ní Ayé”

Àwọn míṣọ́nnárì tó lé ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) ló ń sìn kárí ayé. Báwo la ṣe ń bójú tó wọn?

Àwọn Èèyàn Ń Jàǹfààní Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì Kárí Ayé

A ní ilé ẹ̀kọ́ pàtàkì kan tá à ń ṣe ní New York, àmọ́ ọ̀pọ̀ ibi kárí ayé làwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti ń wá síbẹ̀. Báwo làwọn akẹ́kọ̀ọ́ yìí ṣe ń débẹ̀?

A Túmọ̀ Àpéjọ Agbègbè “Ẹ Máa Yọ̀ Nígbà Gbogbo”! ti Ọdún 2020

Kí ló mú kó ṣeé ṣe fún wa láti tètè túmọ̀ àwọn àsọyé, fídíò àtàwọn orin sí èdè tó lé ní ọgọ́rùn-ún márùn-ún?

À Ń Ṣèpàdé Látorí Ẹ̀rọ Ayélujára

Báwo ni ètò Ọlọ́run ṣe ran ìjọ lọ́wọ́ kí wọ́n lè máa ṣèpàdé lórí ètò ìṣiṣẹ́ Zoom?

ÌRÀNWỌ́ NÍGBÀ ÀJÁLÙ

Bá A Ṣe Ṣèrànwọ́ Nígbà Àjálù Lọ́dún 2022—A Fi Hàn Pé A Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Ará

Báwo la ṣe ṣèrànwọ́ fáwọn tí àjálù ṣẹlẹ̀ sí lọ́dún 2022?

A Ṣètò Ìrànwọ́ Lásìkò ‘Ogun, àti Ìròyìn Nípa Àwọn Ogun’

Ọ̀nà wo la gbà ń ṣètò ìrànwọ́ fáwọn ará wa lórílẹ̀-èdè Ukraine láìka ogun tó ń jà sí? Báwo lèyí sì ṣe rí lára wọn?

Bá A Ṣe Pèsè Ìrànwọ́ Lọ́dún 2021—A Ò Pa Àwọn Arákùnrin Àtàwọn Arábìnrin Wa Tì

Lọ́dún 2021, a ṣèrànwọ́ fáwọn ará wa láwọn orílẹ̀-èdè kan tí àrùn Corona àtàwọn àjálù míì ti fojú wọn rí màbo.

A Ṣètò Ìrànwọ́ Fáwọn Ará Kárí Ayé Nígbà Àjàkálẹ̀ Àrùn

Àwọn ará àtàwọn tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọyì ètò ìrànwọ́ tá a ṣe nígbà àrùn Corona.

A Pèsè Ìrànwọ́ Fáwọn Tí Àjálù Ṣẹlẹ̀ Sí

Lọ́dún iṣẹ́ ìsìn 2020, àrùn Corona àtàwọn àjálù míì mú kí nǹkan nira fún ọ̀pọ̀ àwọn ará wa. Báwo la ṣe ràn wọ́n lọ́wọ́?

Máà bínú, kò sóhun tó jọ ohun tó ò ń wá.